Greg Grunberg
From Wikipedia, the free encyclopedia
Gregory Phillip Grunberg (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù keje ọdún 1966) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Eric Weiss nínú eré ABC tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Alias, Matt Parkman nínú eré NBC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Heroes, Temmin "Snap" Wexley nínú Star Wars: The Force Awakens àti Star Wars: The Rise of Skywalker, àti Phil nínú A Star Is Born. Ó farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré tí J. J. Abrams, ẹni tí ó jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀ dárí bi àpẹẹrẹ, Felicity nínú Sean Blumberg. Ó tún ṣeré nínú eré Showtime tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Masters of Sex.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Greg Grunberg | |
---|---|
Grunberg ní Phoenix Comic Fest ní ọdún 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Gregory Phillip Grunberg 11 Oṣù Keje 1966 (1966-07-11) (ọmọ ọdún 57) Los Angeles, California |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1990–present |
Olólùfẹ́ | Àdàkọ:Married |
Àwọn ọmọ | 3 |
Close