Florence Kasumba
From Wikipedia, the free encyclopedia
Florence Kasumba (tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1976) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Uganda àti Jamini. Ọ̀pọ̀ mọ́ fún ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí enikan tí ó ń jẹ́ ayọ̀ nínú fíìmù àwọn fíìmù ilé isé Marvel Cinematic Universe bi Captain America: Civil War (2016), Black Panther (2018), Avengers: Infinity War (2018), àti Black Panther: Wakanda Forever (2022), ó tún kó ipa ayò nínú fíìmù Disney+ tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ The Falcon and the Winter Soldier (2021). Ó gbajúmọ̀ fún ṣíṣe eré nínú àwọn fíìmù Jámánì àti Dutch. Ó tún kó ipa gẹ́gẹ́ bi Senator Acantha nínú Wonder Woman (2017), Shenzi nínú The Lion King (2019), àti Wicked Witch of the East nínú fíìmù NBC tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ Emerald City (2017).
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Florence Kasumba | |
---|---|
Kasumba at The Lion King European premiere in 2019 | |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹ̀wá 1976 (1976-10-26) (ọmọ ọdún 47) Kampala, Uganda |
Orílẹ̀-èdè | Jamini |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Fontys University of Applied Sciences in Tilburg, the Netherlands |
Iṣẹ́ | Òṣerébìnrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 2001–present |
Website | Àdàkọ:Official URL |
Close