Danny Glover
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Daniel Lebern Glover ( /ˈɡlʌvər/; ọjọ́ìbí July 22, 1946) ni òṣeré, olùdarí fílmù, àti alákitiyan ọ̀ṣèlú ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ìṣeré rẹ̀ bíi Roger Murtaugh nínú àwọn fílmù Lethal Weapon. Ó ṣeré nínú àwọn fílmù bíi The Color Purple (1985), To Sleep with Anger (1990), Predator 2 (1990), Angels in the Outfield (1994) àti Operation Dumbo Drop (1995). Glover tún kópa nínú àwọn fílmù bíi Silverado (1985), Witness (1985), Saw (2004), Shooter (2007), 2012 (2009), Death at a Funeral (2010), Beyond the Lights (2014), Dirty Grandpa (2016), àti Sorry to Bother You (2018). Glover jẹ́ alákitiyan ọ̀rọ̀ ọ̀ṣèlú.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Danny Glover | |
---|---|
Glover in 2014 | |
Ọjọ́ìbí | Daniel Lebern Glover 22 Oṣù Keje 1946 (1946-07-22) (ọmọ ọdún 77) San Francisco, California, U.S. |
Orílẹ̀-èdè | American |
Iṣẹ́ | Actor, director, activist |
Ìgbà iṣẹ́ | 1978–present |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 1 |
Website | louverturefilms.com |
Close