Bhùtán
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ileoba ile Bhutan (pípè /buːˈtɑːn/) je orile-ede tileyika ni Guusu Asia, to budo si apailaorun eti awon Oke Himalaya o si ni bode ni guusu, ilaorun ati iwoorun pelu orile-ede Olominira ile India ati ni ariwa pelu Tibet. Awon ara Bhutan n pe orile-ede won ni Druk Yul (Dzongkha: [འབྲུག་ཡུལ་ 'drug yul] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) to tumo si "Ile Dragon" ni ede Tibet.[7] Awon ara Bhutan je eya eniyan Tibet. Bakanna wo tun ni esin ati asa pelu awon ara Tibet.
Quick Facts Ilẹ̀ọba ilẹ̀ BhùtánKingdom of Bhutan འབྲུག་ཡུལ་Brug rGyal-Khab (Wylie)Dru Gäkhap, Olùìlú ...
Ilẹ̀ọba ilẹ̀ Bhùtán Kingdom of Bhutan འབྲུག་ཡུལ་ Brug rGyal-Khab (Wylie) Dru Gäkhap | |
---|---|
Orin ìyìn: Druk Tsendhen | |
Olùìlú | Thimphu |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Dzongkha |
Orúkọ aráàlú | Bhutanese |
Ìjọba | Constitutional democratic monarchy |
• King | Jigme Khesar Namgyel Wangchuck (འཇིགས་མེད་གེ་སར་རྣམ་རྒྱལ་དབང་ཕྱུག་) |
• Prime Minister | Tshering Tobgay (ཚེ་རིང་སྟོབས་རྒྱས།) |
Formation Early 17th century | |
• Wangchuk Dynasty | 17 December 1907 |
• Constitutional Monarchy | 2007 |
Ìtóbi | |
• Total | 38,394 km2 (14,824 sq mi) |
• Omi (%) | <1 (estimate) |
Alábùgbé | |
• July 2009 estimate | 691,141[1] (163rd) |
• 2005 census | 634,982[2] |
• Ìdìmọ́ra | 18.1/km2 (46.9/sq mi) (154th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $3.518 billion[3] |
• Per capita | $5,212[3] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $1.269 billion[3] |
• Per capita | $1,880[3] |
HDI (2007) | ▲ 0.619[4] Error: Invalid HDI value · 132nd |
Owóníná | Ngultrum2 (BTN) |
Ibi àkókò | UTC+6:00 (BTT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+6:00 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | 975 |
ISO 3166 code | BT |
Internet TLD | .bt |
|
Close
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |